• Home
  • About Us
  • Contact Us
Saturday, July 5, 2025
  • Home
  • News
  • Politics
  • Fanfare
  • Culture
  • Education
  • Entertainment
  • Health
  • Travel and Tourism
  • More
    • Editorial
    • Business
    • Crime and Security
    • Opinion
    • Sports
No Result
View All Result
  • Home
  • News
  • Politics
  • Fanfare
  • Culture
  • Education
  • Entertainment
  • Health
  • Travel and Tourism
  • More
    • Editorial
    • Business
    • Crime and Security
    • Opinion
    • Sports
No Result
View All Result
No Result
View All Result

Alakojanu-Ile Igbimọ Asofin Ọyọ, Gbenga Oyekọla Da’ba lati Gbe Ise Agbẹ Larugẹ, Dena Ebi O Pa ‘Gba Fọwọ Meke Ni Ipiinlẹ Oyo ati Orilede Naijiria.

Peter Olajide by Peter Olajide
March 1, 2024
in Uncategorized
0
Alakojanu-Ile Igbimọ Asofin Ọyọ, Gbenga Oyekọla Da’ba lati Gbe Ise Agbẹ Larugẹ, Dena Ebi O Pa ‘Gba Fọwọ Meke Ni Ipiinlẹ Oyo ati Orilede Naijiria.
3.3k
VIEWS

You might also like

Oyo lawmaker, Wale Canada, Celebrates Alhaji Lateef Yusuff on His Birthday ….Describes Him as a Distinguished Father, Philanthropist, and Mentor to Many

Afonja Joins Ibadan Indigenes to Celebrate Olubadan’s 90th Birthday, First Coronation Anniversary

July 4, 2025
OTOPE 2022 Struggle – And He Never Stopped Caring for His People

OTOPE 2022 Struggle – And He Never Stopped Caring for His People

July 3, 2025

...To get all news updates, Join our WhatsApp Group (Click Here)

Alakojanu-Ile Igbimọ Asofin Ọyọ, Gbenga Oyekọla Da’ba lati Gbe Ise Agbẹ Larugẹ, Dena Ebi O Pa ‘Gba Fọwọ Meke Ni Ipiinlẹ Oyo ati Orilede Naijiria.

Alakojanu-Ile Igbimo Asofin Ipinlẹ Ọyọ, ti o n soju Ijoba Ibilẹ Atiba, Asofin Gbenga Joseph Oyekola ti Da’ba Ofin pe, o se pataki lati gbe Ise Agbẹ Larugẹ, lati dena Ebi O Pa ‘Gba Fowo Meke ni Ipinlẹ Ọyọ.

Nigba to n sagbekale aba ohun, ni Ile Igbimo Asofin Ipinle Oyo Lana, Asofin Gbenga Oyekola Woye pe bi oja ounjẹ se n gbowo’ari ni isẹju isẹju läkoko yi, ti a ko ba gbagbe Aare Orileede yi Aare Hämed Tinubu kede nkan o fi araro ni eka onje ni orilede, eyi ti o fi pase ki won o si ibudo ikounje pamo si, ki o le bu tutu si isoro ebi opa ‘gba fowo meke lawujo Naijiria.

Ẹwẹ, Oyekola Kiyesi pe ailaso lorun Paaka o to apero fun omo Eriwo, ise agbe ti n wokun la ni Ipinle yi, ti a ba woye awon isoro ti n koju awon agbe bii, fifi eran je oko, pipa awon agbe sinu oko, owo bantu ti ise ak pe fun ni akoko yi ati beebe in Iwadi fi han pe ni odun meji sẹyin awon agbẹ npa oko sare kan ni egberur medogun naira, ni odun ti o koja owo na fe fere odi ogun egberun naira, ni asiko yi ora tun ti beyin yo nigbati awon egbe oni katakata (Tractor workers) ti pinu lati gbe owo won soke si ogbon egberun ole marun naira, (#35,000.00k).

Eleyin pe akiyesi wa si owo gege ti a o ma fi ra awon ounje ti ko ba si igbese kanmonkia.

Siwajú asikò ví ni awon odun die seyin, ijoba ipinlẹ Oyo ti seto yiya awon agbe oni katakara ni Owo láti fi pa oko won pelú owo taseré. Wón se ibudó iya katakara si awon ekun kookan tí ani ni Ipinlệ Ọyo, ní Igbana eléyí je okan ninu Iranwo ti ijoba se fun awon agbe tí ó sì té won lorun yato sí awon èta tí óle má kan awon agbe to wa ni oko lara. Fun apeere èto owoya tí ljoba Apapo ati ti Ipinte gbe kale fun awon agbe ní o nira die lati ri gba fún agbe, tía bắ wo lana tí o wa lati gba owo ví, pupo awon torí owo vó ví yi gba ni awon agbe tí wón de tai morùn tí won joko sínu yara oloyé.

Also Read:  Photos News: Oyo Govt presents payment debit cards to over 5000 Beneficiaries

Oyekola tunbo kiyesi pe, ni abala awon olutaja, aisi igbimo ti on se amojuto idiyele lori oja ti ta ti fun awon onisowo ni aanfani lati ma ta awon oja won ni iye ti o ba wu won. Eyi ti o tubo ndi eru to wuwo kun isoro eyi to ti gba Orilede kan. Sise akopamo ounje lati odo awon onisowo naa ko kere ninu isoro ti awujo nkoju.

Alakojanu-Ile tubo gbarata pe, isoro owon gogo oúnje ti so opolopò báále di eni tó rí i ìdaji jade tí yió sì wolé ní aajin dudu latarí pé kò sí ona abayo lati fun ebi re ni jije ati miimu. Eleyi ko sèyin bí awon ohun ti enu nje se n gbowo lórí. Awon ohun jije bi isu, Iresi, epo pupa, ata, tomato, elùbo, agbado gaari ati beebé lò. Adarí ilé, osisé ti o wa ni ipele owo osu kejo le dása mo lounje nie pelu ibi tí nkan won de, gbogbo onise owo ni kò mo ona abayo lati mó fi bo ebi rè, lai da owo bo enu. Adari ile ko si ohun ti won pe ni iyan to ju eyi ti onba wa finra ní awujo wa loni.

O Woye pe, sise itoju ati iranwo ododo fun awon agbe je ona pataki láti bu omi tutti si isoro owon gogo ounje lásiko yi ti se pataki fun ijoba ni gbogbo (cal sectors) ęka lati ko ibi ara si ise agbe laruge yato fun ariwo lásan lori ero ayelu jara (internet). Orilede kan ko le kése jari ninu eto oro aje ti irufe oriléède na ba rogbokun sori kiko ounje wole lati oke-okun.

Also Read:  You did really well and we were all proud of you, Ọmọ Ìyá Kunmi Congratulates Mogaji Akin Fagbemi On New Appointment

O tun Gbarata pé, iroyin fi tówa létí pé ní òsẽ bí meji seyin, Gómina Ipinle Anambra Omowe Soludo latari owo igbeni nigbuwó tí ó rí gba lati ljoba Apapo rá igba merin (800) ero apako (tractor) èyí tí won pín fún àwon agbe lofe, eleyi wayé latări ki oúnje ole sun wốn bồ lópo yanturu, sé tí ebi bá kúrò nínú isẹ, isẹ buse.

Oyekola tun woye pe ijoba Ipinle Oyo labe Ololajulo wa, Gomina Seyi Makinde ti te pepe orisirisi eto k’ebi ma palu ninu ijoba re, ninu eyi ti a ti ri agbekale ajo “SAFER” sise igbe laruge Ibudo awon agbe si ti igbalode (Farm Estates). Bakanna ni eto eyawo fun awon agbę naa ko gbeyin. Sugbon pelu gbogbo eto yi onje tubo ngbowo lori. Fun apere, apo iresi kan ni osu die seyin koju egberun lona ogbon ole marun naira lo (N35,000), loni apo iręsi ti le ni ogorin egberun naira (over eighty thousand N80,000.00k)

Leyin eyi ni Alakojanu-Ile ati Igbimo Asofin Ipinle Oyo pinu lati ro Èka Aláse ljoba pe;

Ni ipase lle Ise Agbę ati Idagbasoke Igberiko (Ministry of Agriculture and Rural Development) lati se dapada awon ibudo iya irinse agbe bi katakara, ero ifinko ati beebelo si awon ekun idibo wa ni ipinle oyo bil Oyo, Ogbomoso, Oke-Ogun, Ibarapa, ati Ibadan.

Bakanna ni ipase lle Ise to n risi eto Okowo, Karakata ati Alajeseku (Ministry of Trade, Investments and Cooperatives) se agbekale Igbimo ti yio ma risi idiyele oja (Price Regulatory Board) ni Ipinle Oyo;

Lati se iranlowo ajile (fertilizers) ati awon irúguin bí a se bú sí asiko ogbin. Nípasę ilé-isé tó n rísí Ètò Oko-Owò, Kárakátà ati Alájeséku (Ministry of Trade, Investments and Cooperatives) gbé gbogbo gbésè tó se lábé ofin láti dèna kiko Oja ońję pamó lóna àitó. Bí ebi bá kúrò nínu ise, sé bùse.

Also Read:  Photos News: Makinde flags off distribution of assorted commodities to vulnerable persons in Oyo

You can get every of our news as soon as they drop on WhatsApp ...To get all news updates, Join our WhatsApp Group (Click Here)
Previous Post

Your Bold Decision To Join PDP Commendable – Agboworin To Shina Peller

Next Post

PDP Iseyin Welcomes Hon. Shina Peller; Labels His Defection as a Blow to Empty Opposition in Oke-Ogun

Peter Olajide

Peter Olajide

Related Stories

Oyo lawmaker, Wale Canada, Celebrates Alhaji Lateef Yusuff on His Birthday ….Describes Him as a Distinguished Father, Philanthropist, and Mentor to Many

Afonja Joins Ibadan Indigenes to Celebrate Olubadan’s 90th Birthday, First Coronation Anniversary

by Peter Olajide
July 4, 2025
0

The former Commissioner for Works and Transport in Oyo State, Professor Abdul-Rahman Raphael Afonja, popularly known as PARA, has felicitated...

OTOPE 2022 Struggle – And He Never Stopped Caring for His People

OTOPE 2022 Struggle – And He Never Stopped Caring for His People

by Peter Olajide
July 3, 2025
0

Let it be on record that Hon. Dr. Temitope Oladimeji, fondly known as Dr. OTOPE, has remained a dedicated and...

Photos News: Hon. Isa Ajibola Oyinlola Hosts Thrilling Football Tournament in Kajola Constituency

Photos News: Hon. Isa Ajibola Oyinlola Hosts Thrilling Football Tournament in Kajola Constituency

by Peter Olajide
June 30, 2025
0

Okeho, Oyo State – June 30, 2025 The grand finale of the much-anticipated Honorable Isa Ajibola Oyinlola Football Competition held...

Rally Behind Our New Oba, Oyo Speaker, Ogundoyin Urges Eruwa Sons and Daughters*

Rally Behind Our New Oba, Oyo Speaker, Ogundoyin Urges Eruwa Sons and Daughters*

by Peter Olajide
June 28, 2025
0

  The Speaker of the Oyo State House of Assembly, Rt. Hon. Adebo Ogundoyin, has called on all indigenes of...

Next Post
PDP Iseyin Welcomes Hon. Shina Peller; Labels His Defection as a Blow to Empty Opposition in Oke-Ogun

PDP Iseyin Welcomes Hon. Shina Peller; Labels His Defection as a Blow to Empty Opposition in Oke-Ogun

Recommended

Oyo lawmaker Hon Babalola Abiodun, PhD. Celebrates Hon Abass Agboworin on His Birthday.

Oyo lawmaker Hon Babalola Abiodun, PhD. Celebrates Hon Abass Agboworin on His Birthday.

June 28, 2025
Oyo Lawmaker, Babajide Celebrates Speaker Adebo Ogundoyin on His Birthday, Hailing His Outstanding Leadership

Oyo Lawmaker, Wale Canada, Mourns the Passing of Oloto of Ofiki, HRH Oba Sunday Adeoye Oyedokun

February 17, 2025

Popular Story

  • Breaking: Ibadan North Rep Member, Akinremi Dies

    Breaking: Ibadan North Rep Member, Akinremi Dies

    1020 shares
    Share 408 Tweet 255
  • Oyo Ad-hoc Staff Appeal to Governor Makinde

    955 shares
    Share 382 Tweet 239
  • Jubilation As Makinde Pays December Salaries Early

    879 shares
    Share 352 Tweet 220
  • Breaking: Ex Oyo Lawmaker, Hon Babatunde Eesuola is dead.

    864 shares
    Share 346 Tweet 216
  • Breaking : Two Years After Becoming Olubadan, Oba Balogun Joins Ancestors At 82

    861 shares
    Share 344 Tweet 215

Stay up-to-date with the latest happenings in Oyo State! From breaking news to in-depth updates on local events, our blog covers it all. Visit us regularly to stay informed about everything that matters in your community

  • Home
  • About Us
  • Contact Us

© 2024 Naija24hrs - Website Designed by Samtech Media (+2348103682435)

No Result
View All Result
  • Home
  • News
  • Politics
  • Fanfare
  • Culture
  • Education
  • Entertainment
  • Health
  • Travel and Tourism
  • Editorial
  • Crime and Security
  • Business
  • Opinion
  • Sports

© 2024 Naija24hrs - Website Designed by Samtech Media (+2348103682435)

Are you sure want to unlock this post?
Unlock left : 0
Are you sure want to cancel subscription?